Òrò arópò ni àwon òrò tí a n lò dípò òrò orúko nínú gbólóhûn. Bí àpeere:
(i) Sadé ra ìwé. > Ó ra ìwé.
"O" ni òrò arópò orúko tí a lò dípò Sadé".
(ii). Bólá àti Bímpé ti lo. > Wón ti lo.
"Wón" ni òrò arópò orúko tí a lò dípò"Bólá" àti " Bímpé" .
(iii). Ajá gbó mó àwon Olè. > Ó gbó mó won.
"Ó" àti "wón" jé òrò arópò orúko. "Ó" ni a lò dípò"Ajá", a sì lo "won" dípò "àwon Olè".
ISÉ TÍ ÒRÒ ARÓPÒ ORÚKO MÁA N
NÍNÚ GBÓLÓHÙN
(i) Òrò arópò orúko lè sisé gégé bí Olùwà,àbò àti èyán nínú gbólóhûn .
(ii) Òrò arópò orúko máa n tóka sí enì kíní, kejì àti enìkéta nínú gbólóhûn.
(iii) Òrò arópò orúko tún máa n ní ètò tí ó máa n tóka sí iye [eyo àti òpò] nínú gbólóhûn.
19 comments:
I love you
Pls I need more explanation on Oro oruko afoyemo ati alaiseeka
Thanks
Good
Thanks so much
Modupe
Please can you also explain Oro aropo afarajoruko
Hi
Thank you very much
So ipo ti a ti le lo oro aropo-oriko.
Thanks so much for these
Oro oruko ni oruko eniyan ,eranko, ibikan ,tabi, nnkan.
Mo gbadun awon owun ti a ko ninu eko Yi. E see fun imole ti e tan sii.
Thanks 😊😘😘😘
I love it
I'm sooo satisfied
Abo
I really appreciate
thanks
Post a Comment