Kíni Àròko?
Aroko tunmo si ohun ti a ro ti a si ko sile ni ona ti yoo gba ye elomiiran lati ka.
ORISI AROKO
1.Aroko oniroyin.
2.Aroko Alapejuwe
3.Aroko Alalaye.
4.Aroko Ariyanjiyan.
5.Aroko onisorongbesi.
6.Aroko Ajemo isipaya
7.Aroko Onileta.abbl.
50 comments:
Pls explain them
Explain them please
Good
ejowo e se alaye orisi aroko yii
Thanks
ALAYE LORI ORISIRI AROKO TI O WA
1.AROKO ONIROYIN:- Eyi je aroko ti a fi n so tabi salaye nipa isele ti o sele ni isoju eniyan.
APEERE ORI ORO AROKO ONIROYIN
a.Ijamba oko ti o sele ni isoju mi.
b.Ayeye iranti ojo ibi mi
d.Ala buburu kan ti o d`eru ba mi
e.ojo buruku esu gbomi mu.abbl.
2.AROKO ALAPEJUWE.
Aroko yii je eyi ti a fi n so ni pato bi nnkan se ri.
APEERE ORI ORO AROKO ALAPEJUWE
a.Ounje ti mo feran ju.
b.Ile iwe mi
d.Aburo mi
e.Oja adugbo mi
e.Ona ile oba ilu wa.abbl.
3.AROKO ALALAYE
Eyi je aroko ti a fi n se alaye nipa nnkan.Eni ti o ba n ko aroko yii maa n wa ni ipo oluko nigba ti eni ti o n ka iru aroko yii maa n wa ni ipo akekoo,nitori pe oluko aroko yii fe se alaye nipa ohun ti a oo mo nipa re tabi ti a o mo bi a se le se sugbon ti a fe ko nipa re.
APEERE IRU AKORI AROKO YII NI:
a.akara dindin
b.Asa ikobinrinjo ni aye atijo
d.Igba ojo
e.Bi a se nko ile ni aye atijo.abbl.(to be cont)
OK.
It will be updated. Thanks
It's done already. Thanks.
E se pupo sir
E se pupo, MO ti se alaye Lori die nibe ki e lo Kaa.
👏👏
Yoruba sun lotito, opolo yin ko ni doba
E SEUN Gan Gan
E se pupo,emi naa fe darapo mo yin o
Pls I want to write aroko lori omo bori owo
Please translate
Please kini awon igbese aroko
Pls,can u explain the other types of aroko. I need them for an exam ASAP.
OK
I also need the explanation of the rest of the orisi aroko
E seun gaan
👏👏👌
E seun gaan
👏👏👌
Àtèjáde rè n bò lónà láì pé.
A dúpé.
N ó báa yín sisé le l'órí.
Ó dára béè.E fi àtèjísé ránsé sími ní: ebenezeralonge97@yahoo.com
Isé wa ni láti tée yín l'órùn.A sì dúpé pe è n bâwa kàá.
E sé,a dúpé.
Olúwa l'ó seé.
You're welcome
ebenezeralonge1@gmail.com
A ti dáhùn ìbéèrè yín, kí e lo kàá.
Tí e bá fé ko àròko Lori "OMO BORÍ OWÓ",ohun àkókó ti e ni láti béèrè lówó Ara yín ni wipe, irú àròko wo ni èyí?
Léyìn tí e to mo irú àròko tí ó jé,ohun tí ó kàn ni:
"KÍKO ORÍ ÒRÒ"(topic).Ìyen ni Ori òrò ti àròko yín fé dálé l'órí.
Léyìn èyí ni ó kàn "ÌFÂÀRÀ"(introduction).
Ohun tí e ó se nibi ni síso nípa kíni OWÓ? àti kini OMO? Se àlàyé ohun tí o mò nípa àwon òrò méjì yii.Léyìn náà,so nípa ìwúlò tàbí ànfààní OWÓ àti OMO, kíni àléébù àwon méjèèjì?
Tí o bá ti se èyí,ipari tàbí ìgúnle ni ó kù.
Ní abé ìgúnle re ni wàá ti faramó èyí ti o lérò wípé ó dára.
ÀKÍYÈSÍ: èyí ti ànfààní rè bá pòju àléébù rè ni ó dára jùlo.
MO L'ÉRÒ WÍPÉ ÈYÍ YÓÒ SE Ó NÍ ÀNFÀÀNÍ.

Noce
Thai
Can you please explain because I don't understand
Sir I need a letter of asa ikobinrinjo
Pls can you tell me a letter of ikobirinjo
Please kini àròkọ alarinyanjiyan
E jowosir alaye Lori alariya jiyan
PLs write on the other aroke like ALALAYE, ARIYANJIYAN AND OTHERS PLEASE AM IN NEED OF IT
Ok
Ok
E how e ko ni pa awon orisi aroko to kun
Ejo e salaye awòn orisirisi aròkó no ekunrere
'
Pls could u kindly explain the remaining
It has been explained.
Post a Comment